Luk 19:8-10

Luk 19:8-10 YBCV

Sakeu si dide, o si wi fun Oluwa pe, Wo o, Oluwa, àbọ ohun ini mi ni mo fifun talakà; bi mo ba si fi ẹ̀sun eke gbà ohun kan lọwọ ẹnikẹni, mo san a pada ni ilọpo mẹrin. Jesu si wi fun u pe, Loni ni igbala wọ̀ ile yi, niwọnbi on pẹlu ti jẹ ọmọ Abrahamu. Nitori Ọmọ-enia de lati wá awọn ti o nù kiri, ati lati gbà wọn là.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ