Luk 17:3-5

Luk 17:3-5 YBCV

Ẹ mã kiyesara nyin: bi arakunrin rẹ ba ṣẹ̀, ba a wi; bi o ba si ronupiwada, dari jì i. Bi o ba si ṣẹ̀ ọ li ẹrinmeje li õjọ, ti o si pada tọ̀ ọ wá li ẹrinmeje li õjọ pe, Mo ronupiwada; dari jì i. Awọn aposteli si wi fun Oluwa pe, Busi igbagbọ́ wa.

Àwọn fídíò fún Luk 17:3-5