Luk 16:16

Luk 16:16 YBCV

Ofin ati awọn woli mbẹ titi di igba Johanu: lati igbana wá li a ti nwasu ijọba Ọlọrun, olukuluku si nfi ipá wọ̀ inu rẹ̀.

Àwọn fídíò fún Luk 16:16