Luk 14:14

Luk 14:14 YBCV

Iwọ o si jẹ alabukun fun; nitori nwọn kò ni ohun ti nwọn o fi san a fun ọ: ṣugbọn a o san a fun ọ li ajinde awọn olõtọ.

Àwọn fídíò fún Luk 14:14