Luk 12:31-32

Luk 12:31-32 YBCV

Ṣugbọn ẹ mã wá ijọba Ọlọrun; gbogbo nkan wọnyi li a o si fi kún nyin. Má bẹ̀ru, agbo kekere; nitori didùn inu Baba nyin ni lati fi ijọba fun nyin.

Àwọn fídíò fún Luk 12:31-32