Luk 1:78-79

Luk 1:78-79 YBCV

Nitori iyọ́nu Ọlọrun wa; nipa eyiti ìla-õrùn lati oke wá bojuwò wa, Lati fi imọlẹ fun awọn ti o joko li òkunkun ati li ojiji ikú, ati lati fi ẹsẹ wa le ọ̀na alafia.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ