Luk 1:74-75

Luk 1:74-75 YBCV

Pe on o fifun wa, lati gbà wa lọwọ awọn ọtá wa, ki awa ki o le ma sìn i laifòya, Ni mimọ́ ìwa ati li ododo niwaju rẹ̀, li ọjọ aiye wa gbogbo.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ