Luk 1:57-58

Luk 1:57-58 YBCV

Ọjọ Elisabeti pe wayi ti yio bí; o si bí ọmọkunrin kan. Ati awọn aladugbo, ati awọn ibatan rẹ̀ gbọ́ bi Oluwa ti ṣe ãnu nla fun u; nwọn si ba a yọ̀.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ