Lef 7:1-2

Lef 7:1-2 YBCV

EYI si li ofin ẹbọ ẹbi: mimọ́ julọ ni. Ni ibi ti nwọn gbé pa ẹbọ sisun ni ki nwọn ki o pa ẹbọ ẹbi: ki o si fi ẹ̀jẹ rẹ̀ wọ́n ori pẹpẹ yiká.