Lef 11:1-2

Lef 11:1-2 YBCV

OLUWA si sọ fun Mose ati fun Aaroni, o wi fun wọn pe, Sọ fun awọn ọmọ Israeli pe, Wọnyi li ẹranko ti ẹnyin o ma jẹ ninu gbogbo ẹran ti mbẹ lori ilẹ aiye.