Awọn ọba aiye, ati gbogbo olugbe ilẹ-aiye, kò gbagbọ pe aninilara ati ọta iba ti wọ inu ẹnu-bode Jerusalemu. Nitori ẹ̀ṣẹ awọn woli rẹ̀, ati aiṣedede awọn alufa rẹ̀, ti nwọn ti ta ẹ̀jẹ awọn olododo silẹ li ãrin rẹ̀. Nwọn ti rin kiri bi afọju ni ita, nwọn di alaimọ́ fun ẹ̀jẹ tobẹ̃ ti enia kò le fi ọwọ kan aṣọ wọn.
Kà Ẹk. Jer 4
Feti si Ẹk. Jer 4
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Ẹk. Jer 4:12-14
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò