Tali ẹniti iwi, ti isi iṣẹ, nigbati Oluwa kò paṣẹ rẹ̀. Ibi ati rere kò ha njade lati ẹnu Ọga-ogo-julọ wá? Ẽṣe ti enia alãye nkùn? ti o wà lãye, ki olukuluku ki o kùn nitori ẹ̀ṣẹ rẹ̀! Jẹ ki a wádi, ki a si dán ọ̀na wa wò, ki a si tun yipada si Oluwa. Jẹ ki a gbe ọkàn ati ọwọ wa soke si Ọlọrun li ọrun.
Kà Ẹk. Jer 3
Feti si Ẹk. Jer 3
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Ẹk. Jer 3:37-41
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò