Ẹk. Jer 3:21-22

Ẹk. Jer 3:21-22 YBCV

Eyi ni emi o rò li ọkàn mi, nitorina emi o ma reti. Ãnu Oluwa ni, ti awa kò parun tan, nitori irọnu-ãnu rẹ kò li opin.