Jud 1:1-2

Jud 1:1-2 YBCV

JUDA, iranṣẹ Jesu Kristi, ati arakunrin Jakọbu, si awọn ti a pè, olufẹ ninu Ọlọrun Baba, ti a si pamọ́ fun Jesu Kristi: Ki ãnu, ati alafia, ati ifẹ ki o mã bi si i fun nyin.