Jon 2:9-10

Jon 2:9-10 YBCV

Ṣugbọn emi o fi ohùn idupẹ rubọ si ọ; emi o san ẹjẹ́ ti mo ti jẹ. Ti Oluwa ni igbala. Oluwa si sọ fun ẹja na, o si pọ̀ Jona sori ilẹ gbigbẹ.