Job 6:11-13

Job 6:11-13 YBCV

Kili agbara mi ti emi o fi dabá? ki si li opin mi ti emi o fi fà ẹmi mi gùn? Agbara mi iṣe agbara okuta bi, tabi ẹran ara mi iṣe idẹ? Iranlọwọ mi kò ha wà ninu mi: ọgbọn ha ti salọ kuro lọdọ mi bi?