Job 3:1-3

Job 3:1-3 YBCV

LẸHIN eyi ni Jobu yanu o si fi ọjọ ibi rẹ̀ ré. Jobu sọ, o si wipe, Ki ọjọ ti a bi mi ki o di igbagbe, ati oru nì, ninu eyi ti a wipe; a loyun ọmọkunrin kan.