Job 2:7-8

Job 2:7-8 YBCV

Bẹ̃ni Satani jade lọ kuro niwaju Oluwa, o si sọ Jobu li õwo kikankikan lati atẹlẹsẹ rẹ̀ lọ de atari rẹ̀. O si mu apadì o fi nhá ara rẹ̀, o si joko ninu ẽru.