Job 11:7-9

Job 11:7-9 YBCV

Iwọ ha le fi awari ri idi Ọlọrun? iwọ le ri idi Olodumare de pipé rẹ̀? O dabi giga ọrun, kini iwọ le iṣe? o jinlẹ jù ipo-okú lọ, kini iwọ le imọ̀? Ìwọn rẹ̀ gùn jù aiye lọ, o si ni ìbu jù okun lọ.