Joh 6:67-68

Joh 6:67-68 YBCV

Nitorina Jesu wi fun awọn mejila pe, Ẹnyin pẹlu nfẹ lọ bi? Nigbana ni Simoni Peteru da a lohùn wipe, Oluwa, Ọdọ tali awa o lọ? Iwọ li o ni ọ̀rọ ìye ainipẹkun.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ