Joh 3:5

Joh 3:5 YBCV

Jesu dahùn wipe, Lõtọ, lõtọ ni mo wi fun ọ, Bikoṣepe a fi omi ati Ẹmi bi enia, on kò le wọ̀ ijọba Ọlọrun.

Àwọn fídíò fún Joh 3:5