Joh 3:34-36

Joh 3:34-36 YBCV

Nitori ẹniti Ọlọrun ti rán nsọ ọ̀rọ Ọlọrun: nitoriti Ọlọrun kò fi Ẹmí fun u nipa oṣuwọn. Baba fẹ Ọmọ, o si ti fi ohun gbogbo le e lọwọ. Ẹniti o ba gbà Ọmọ gbọ́, o ni iye ainipẹkun: ẹniti kò ba si gbà Ọmọ gbọ, kì yio ri ìye; ṣugbọn ibinu Ọlọrun mbẹ lori rẹ̀.

Àwọn fídíò fún Joh 3:34-36