Joh 20:29

Joh 20:29 YBCV

Jesu wi fun u pe, Nitoriti iwọ ri mi ni iwọ ṣe gbagbọ́: alabukun-fun li awọn ti kò ri, ti nwọn si gbagbọ́.

Àwọn fídíò fún Joh 20:29