Joh 2:4-5

Joh 2:4-5 YBCV

Jesu wi fun u pe, Kini ṣe temi tirẹ, obinrin yi? wakati mi kò iti de. Iya rẹ̀ wi fun awọn iranṣẹ pe, Ohunkohun ti o ba wi fun nyin, ẹ ṣe e.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ