Joh 17:15-16

Joh 17:15-16 YBCV

Emi ko gbadura pe, ki iwọ ki o mu wọn kuro li aiye, ṣugbọn ki iwọ ki o pa wọn mọ́ kuro ninu ibi. Nwọn kì iṣe ti aiye, gẹgẹ bi emi kì ti iṣe ti aiye.

Àwọn fídíò fún Joh 17:15-16