Joh 16:1-2

Joh 16:1-2 YBCV

NKAN wọnyi ni mo ti sọ fun nyin, ki a má ba mu nyin kọsẹ̀. Nwọn o yọ nyin kuro ninu sinagogu: ani, akokò mbọ̀, ti ẹnikẹni ti o ba pa nyin, yio rò pe on nṣe ìsin fun Ọlọrun.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ