Joh 15:1-3

Joh 15:1-3 YBCV

EMI ni àjara tõtọ, Baba mi si ni oluṣọgba. Gbogbo ẹká ninu mi ti kò ba so eso, on a mu u kuro: gbogbo ẹka ti o ba si so eso, on a wẹ̀ ẹ mọ́, ki o le so eso si i. Ẹnyin mọ́ nisisiyi nitori ọ̀rọ ti mo ti sọ fun nyin.

Àwọn fídíò fún Joh 15:1-3

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Joh 15:1-3

Joh 15:1-3 - EMI ni àjara tõtọ, Baba mi si ni oluṣọgba.
Gbogbo ẹká ninu mi ti kò ba so eso, on a mu u kuro: gbogbo ẹka ti o ba si so eso, on a wẹ̀ ẹ mọ́, ki o le so eso si i.
Ẹnyin mọ́ nisisiyi nitori ọ̀rọ ti mo ti sọ fun nyin.Joh 15:1-3 - EMI ni àjara tõtọ, Baba mi si ni oluṣọgba.
Gbogbo ẹká ninu mi ti kò ba so eso, on a mu u kuro: gbogbo ẹka ti o ba si so eso, on a wẹ̀ ẹ mọ́, ki o le so eso si i.
Ẹnyin mọ́ nisisiyi nitori ọ̀rọ ti mo ti sọ fun nyin.

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Joh 15:1-3