Joh 10:4

Joh 10:4 YBCV

Nigbati o si mu awọn agutan tirẹ̀ jade, o ṣiwaju wọn, awọn agutan si ntọ̀ ọ lẹhin: nitoriti nwọn mọ̀ ohùn rẹ̀.

Àwọn fídíò fún Joh 10:4