Joh 10:15

Joh 10:15 YBCV

Gẹgẹ bi Baba ti mọ̀ mi, ti emi si mọ̀ Baba; mo si fi ẹmí mi lelẹ nitori awọn agutan.

Àwọn fídíò fún Joh 10:15