Joh 1:19-21

Joh 1:19-21 YBCV

Eyi si li ẹrí Johanu, nigbati awọn Ju rán awọn alufã ati awọn ọmọ Lefi lati Jerusalemu wá lati bi i lẽre pe, Tani iwọ ṣe? O si jẹwọ, kò si sẹ́; o si jẹwọ pe, Emi kì iṣe Kristi na. Nwọn si bi i pe, Tani iwọ ha iṣe? Elijah ni ọ bi? O si wipe Bẹ̃kọ. Iwọ ni woli na bi? O si dahùn wipe, Bẹ̃kọ.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ