Jer 32:38-39

Jer 32:38-39 YBCV

Nwọn o si jẹ enia mi, emi o si jẹ Ọlọrun wọn. Emi o si fun wọn li ọkàn kan, ati ọ̀na kan, ki nwọn ki o le bẹ̀ru mi li ọjọ gbogbo, fun rere wọn, ati ti awọn ọmọ wọn lẹhin wọn