A. Oni 9:52-53

A. Oni 9:52-53 YBCV

Abimeleki si wá si ibi ile-ẹṣọ́ na, o si bá a jà, o si sunmọ ẹnu-ọ̀na ile-ẹṣọ na lati fi iná si i. Obinrin kan si sọ ọlọ lù Abimeleki li ori, o si fọ́ ọ li agbári.