A. Oni 14:14

A. Oni 14:14 YBCV

O si wi fun wọn pe, Lati inu ọjẹun li onjẹ ti jade wá, ati lati inu alagbara li adùn ti jade wá. Nwọn kò si le já alọ́ na nìwọn ijọ́ mẹta.