Nitori o ṣakiyesi ara rẹ̀, o si ba tirẹ̀ lọ, lojukanna o si gbagbé bi on ti ri. Ṣugbọn ẹniti o ba nwo inu ofin pipé, ofin omnira nì, ti o si duro ninu rẹ̀, ti on kò jẹ olugbọ́ ti ngbagbé, bikoṣe oluṣe iṣẹ, oluwarẹ̀ yio jẹ alabukun ninu iṣẹ rẹ̀. Bi ẹnikẹni ba ro pe on nsìn Ọlọrun nigbati kò kó ahọn rẹ̀ ni ijanu, ṣugbọn ti o ntàn ọkàn ara rẹ̀ jẹ, ìsin oluwarẹ̀ asan ni. Ìsin mimọ́ ati ailẽri niwaju Ọlọrun ati Baba li eyi, lati mã bojutó awọn alainibaba ati awọn opó ninu ipọnju wọn, ati lati pa ara rẹ̀ mọ́ lailabawọn kuro li aiyé.
Kà Jak 1
Feti si Jak 1
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Jak 1:24-27
3 Awọn ọjọ
Ninu ifọkansi ti ọsẹ yii, a fẹ lati wo awọn ipele oriṣiriṣi ti o waye ṣaaju ki igbagbọ eniyan le gbe awọn abajade ojulowo ati deede jade. Adura mi ni pe ki oluka yoo lo awọn ilana ti yoo pin nibi ni ọsẹ yii ni orukọ Jesu.
5 Days
It’s easy to feel overwhelmed, ill-equipped, and just plain lost when it comes to God's Word. My aim is to simplify the process of Bible Study for you in a few ways by teaching you three of the most important principles of successful Bible Study. Join this plan and discover how to read the Bible not just for information, but for life transformation today!
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò