Isa 35:5-6

Isa 35:5-6 YBCV

Nigbana li oju awọn afọju yio là, eti awọn aditi yio si ṣi. Nigbana li awọn arọ yio fò bi agbọ̀nrin, ati ahọ́n odi yio kọrin: nitori omi yio tú jade li aginju, ati iṣàn omi ni ijù.