Isa 32:16-19

Isa 32:16-19 YBCV

Nigbana ni idajọ yio ma gbe aginju; ati ododo ninu ilẹ eleso. Iṣẹ ododo yio si jẹ alafia, ati eso ododo yio jẹ idakẹjẹ on ãbo titi lai. Awọn enia mi yio si ma gbe ibugbe alafia, ati ni ibugbe idaniloju, ati ni ibi isimi iparọrọ; Ṣugbọn yio rọ̀ yìnyín, nigbati igbó nṣubu lulẹ; ati ni irẹlẹ a o rẹ̀ ilu na silẹ.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Isa 32:16-19

Isa 32:16-19 - Nigbana ni idajọ yio ma gbe aginju; ati ododo ninu ilẹ eleso.
Iṣẹ ododo yio si jẹ alafia, ati eso ododo yio jẹ idakẹjẹ on ãbo titi lai.
Awọn enia mi yio si ma gbe ibugbe alafia, ati ni ibugbe idaniloju, ati ni ibi isimi iparọrọ;
Ṣugbọn yio rọ̀ yìnyín, nigbati igbó nṣubu lulẹ; ati ni irẹlẹ a o rẹ̀ ilu na silẹ.