Kiyesi i, Ọlọrun ni igbala mi; emi o gbẹkẹle, emi ki yio si bẹ̀ru: nitori Oluwa Jehofah li agbara mi ati orin mi; on pẹlu si di igbala mi. Ẹnyin o si fi ayọ̀ fà omi jade lati inu kanga igbala wá. Li ọjọ na li ẹnyin o si wipe, Yìn Oluwa, kepe orukọ rẹ̀, sọ iṣẹ́ rẹ̀ lãrin awọn enia, mu u wá si iranti pe, orukọ rẹ̀ li a gbe leke. Kọrin si Oluwa: nitori o ti ṣe ohun didara: eyi di mimọ̀ ni gbogbo aiye. Kigbe, si hó, iwọ olugbe Sioni: nitori ẹni titobi ni Ẹni-Mimọ́ Israeli li ãrin rẹ.
Kà Isa 12
Feti si Isa 12
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Isa 12:2-6
7 Days
Every day has the potential to introduce complex new challenges into our lives. But it’s equally likely that each new day will gift us with exciting new opportunities. In this seven-day devotional, staff members at YouVersion help you apply truths from God’s Word to whatever you’re facing today. Each day’s devotional includes a Verse Image to help you share what God is speaking to you.
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò