Heb 10:17-18

Heb 10:17-18 YBCV

Ẹ̀ṣẹ wọn ati aiṣedede wọn li emi kì yio si ranti mọ́. Ṣugbọn nibiti imukuro iwọnyi ba gbé wà, irubọ fun ẹ̀ṣẹ kò si mọ́.