Gẹn 38:9-10

Gẹn 38:9-10 YBCV

Onani si mọ̀ pe, irú-ọmọ ki yio ṣe tirẹ̀; o si ṣe bi o ti wọle tọ̀ aya arakunrin rẹ̀ lọ, o si dà a silẹ, ki o má ba fi irú-ọmọ fun arakunrin rẹ̀. Ohun ti o si ṣe buru loju OLUWA, nitori na li OLUWA pa a pẹlu.