Gẹn 28:10-11

Gẹn 28:10-11 YBCV

Jakobu si jade kuro lati Beer-ṣeba lọ, o si lọ si ìha Harani. O si de ibi kan, o duro nibẹ̀ li oru na, nitori õrùn wọ̀; o si mu ninu okuta ibẹ̀ na, o fi ṣe irọri rẹ̀, o si sùn nibẹ̀ na.