Gẹn 21:9-11

Gẹn 21:9-11 YBCV

Sara si ri ọmọ Hagari, ara Egipti, ti o bí fun Abrahamu, o nfi i rẹrin. Nitorina li o ṣe wi fun Abrahamu pe, Lé ẹrubirin yi jade ti on ti ọmọ rẹ̀: nitoriti ọmọ ẹrubirin yi ki yio ṣe arole pẹlu Isaaki, ọmọ mi. Ọrọ yi si buru gidigidi li oju Abrahamu nitori ọmọ rẹ̀.