Gẹn 19:36-38

Gẹn 19:36-38 YBCV

Bẹ̃li awọn ọmọbinrin Loti mejeji loyun fun baba wọn. Eyi akọ́bi si bí ọmọkunrin kan, o si pè orukọ rẹ̀ ni Moabu: on ni baba awọn ara Moabu titi di oni. Eyi atẹle, on pẹlu si bí ọmọkunrin kan, o si pè orukọ rẹ̀ ni Ben-ammi: on ni baba awọn ọmọ Ammoni, titi di oni.