Gẹn 11:29-30

Gẹn 11:29-30 YBCV

Ati Abramu ati Nahor si fẹ aya fun ara wọn: orukọ aya Abramu ni Sarai; ati orukọ aya Nahori ni Milka, ọmọbinrin Harani, baba Milka, ati baba Iska. Ṣugbọn Sarai yàgan; kò li ọmọ.