Gẹn 1:2-3

Gẹn 1:2-3 YBCV

Aiye si wà ni jũju, o si ṣofo; òkunkun si wà loju ibú: Ẹmi Ọlọrun si nràbaba loju omi. Ọlọrun si wipe, Ki imọlẹ ki o wà: imọlẹ si wà.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Gẹn 1:2-3

Gẹn 1:2-3 - Aiye si wà ni jũju, o si ṣofo; òkunkun si wà loju ibú: Ẹmi Ọlọrun si nràbaba loju omi.
Ọlọrun si wipe, Ki imọlẹ ki o wà: imọlẹ si wà.