Esr 2:64-65

Esr 2:64-65 YBCV

Apapọ gbogbo ijọ na, jẹ ẹgbã mọkanlelogun o le ojidinirinwo. Li aika iranṣẹkunrin wọn ati iranṣẹbinrin wọn, ti o jẹ ẹgbẹrindilẹgbãrin o din mẹtalelọgọta: igba akọrin ọkunrin ati akọrin obinrin li o si wà ninu wọn.