Awọn kerubu si gbe iyẹ́ wọn soke, pelu awọn kẹkẹ́ lẹgbẹ wọn, ogo Ọlọrun Israeli si wà lori wọn loke. Ogo Oluwa si goke lọ kuro lãrin ilu na; o si duro lori oke-nla, ti o wà nihà ila-õrùn ilu na. Lẹhin na ẹmi gbe mi soke, o si mu mi wá si Kaldea li ojuran, nipa Ẹmi Ọlọrun sọdọ awọn ti igbekun. Bẹ̃ni iran ti mo ti ri lọ kuro lọdọ mi. Mo si sọ gbogbo ohun ti Oluwa ti fi hàn mi fun awọn ti igbekùn.
Kà Esek 11
Feti si Esek 11
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Esek 11:22-25
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò