OLUWA si wi fun Mose pe, Emi o ṣe ohun yi ti iwọ sọ pẹlu: nitoriti iwọ ri ore-ọfẹ li oju mi, emi si mọ̀ ọ li orukọ. O si wi fun u pe, Emi bẹ̀ ọ, fi ogo rẹ̀ hàn mi. On si wi fun u pe, Emi o mu gbogbo ore mi kọja niwaju rẹ, emi o si pè orukọ OLUWA niwaju rẹ; emi o si ṣe ore-ọfẹ fun ẹniti emi nfẹ ṣe ore-ọfẹ fun, emi o si ṣe ãnu fun ẹniti emi o ṣe ãnu fun. On si wipe, Iwọ kò le ri oju mi: nitoriti kò sí enia kan ti iri mi, ti si yè. OLUWA si wipe, Wò, ibi kan wà lẹba ọdọ mi, iwọ o si duro lori apata: Yio si ṣe, nigbati ogo mi ba nrekọja, emi o fi ọ sinu palapala apata, emi o si fi ọwọ́ mi bò ọ titi emi o fi rekọja: Nigbati emi o mú ọwọ́ mi kuro, iwọ o si ri akẹhinsi mi: ṣugbọn oju mi li a ki iri.
Kà Eks 33
Feti si Eks 33
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Eks 33:17-23
5 Days
Are you experiencing a wilderness season, finding no water or oasis for your soul? What if this season held the greatest hope of all: to know God’s Presence intimately, authentically, and passionately? This devotional encourages you that this time is not wasted, though some days you feel as if you are going nowhere. Because no matter what terrain you tread, God is journeying with you as Comforter, Life-giver, & Friend.
8 Days
This is week one in a seven-week series that walks you through the struggles of anxiety while holding to biblical truth and God’s promises. This eight-day plan provides encouragement and practical application to align your heart and mind with the love of Jesus in the midst of anxiety. This week’s promise: God is with me.
16 Days
We’re taught from early on that God is our Father and we are His children. But relating to God as Father isn’t always easy—especially if our earthly dads struggled to show the love we longed for. In this 16-day study, Pete Briscoe draws our attention to the God who satisfies all our longings for love—highlighting how Scripture reveals Him to be our good and perfect Father.
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò