Eks 20:12-14

Eks 20:12-14 YBCV

Bọ̀wọ fun baba on iya rẹ: ki ọjọ́ rẹ ki o le pẹ ni ilẹ ti OLUWA Ọlọrun rẹ fi fun ọ. Iwọ kò gbọdọ pania. Iwọ kò gbọdọ ṣe panṣaga.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Eks 20:12-14

Eks 20:12-14 - Bọ̀wọ fun baba on iya rẹ: ki ọjọ́ rẹ ki o le pẹ ni ilẹ ti OLUWA Ọlọrun rẹ fi fun ọ.
Iwọ kò gbọdọ pania.
Iwọ kò gbọdọ ṣe panṣaga.