Eks 20:1-3

Eks 20:1-3 YBCV

ỌLỌRUN si sọ gbogbo ọ̀rọ wọnyi pe, Emi li OLUWA Ọlọrun rẹ, ti o mú ọ jade lati ilẹ Egipti, lati oko-ẹrú jade wá. Iwọ kò gbọdọ lí Ọlọrun miran pẹlu mi.