Eks 17:12-13

Eks 17:12-13 YBCV

Ṣugbọn ọwọ́ kún Mose; nwọn si mú okuta kan, nwọn si fi si abẹ rẹ̀, o si joko lé e; Aaroni ati Huri si mu u li ọwọ́ ró, ọkan li apa kini, ekeji li apa keji; ọwọ́ rẹ̀ si duro gan titi o fi di ìwọ-õrùn. Joṣua si fi oju idà ṣẹgun Amaleki ati awọn enia rẹ̀ tútu.